Smiley face

'Otito Ni Mo Fun Ekeji Mi Ni Noku Legbe Orun" -Peter Okoye (P-square)

Awon kan lo tun gbe awuyewuye kan dide eleyii to n wi pe abamoda ni ija ti won lo waye laaarin awon omo meji olorin. Ohun ti won so ni wi pe boya ija kankan ko tile waye rara to je wi pe won n wa ogbon lati je ki awon eniyan maa je oro won lenu bi igba eniyan n je orogbo. Sugbon Peter ti je ko ye wa wi pe otito ni oun ja pelu ekeji oun. O ni iru ija bee si maa n sele ninu ebi, ija laaarin egbon ati aburo. Awon mejeeji ti pada si enu ise won bayii, gbogbo nnkan si ti pada si bo se wa tele. 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment