Smiley face

A Ku Ewu Omo Tuntun ooooo


Ogbontarigi agbaboolu ile Nigeria, Osaze Odemwingie bi omo tuntun lonii (May 15th,2014),gbogbo wa pata labayo fun ohun tuntun fi Oba oke fi ta idile re lore. Omokeji re e leyin igba ti won ti se igbeyawo losu karun-un odun 2012.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment