Se ki n se wi pe omokunrin ti won n pe ni Denrele yii fe dabi Micheal Jackson? E wo oju Ayefele bo se dabi eniyan gidi, e tun wa wo ti Denrele bo se dabi eniyan 'pataki'. Mmmmmmmmmh! Pelu bi awon mejeeji se ri yii ta lo wu yin lati ba ya foto, Denrele tabi Ayefele? Idahun yin maa ran wa lowo pupo. E se. (lol)
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
denrele ti di ebora ki nse eniyan mo...... Ayefele ni emi ma ba ya photo o
ReplyDeleteIs Ayefele but what happen to denrele why did he be like that?
ReplyDelete