Igba ti oniwaasu Goodheart Ekwueme waasu tan eleyii ti akole iwaasu re je "Feran Oluwa ati enikeji re" ni alufa gbe ero gbohungbohun le Aare lowo lati ba awon eniyan soro to se pataki.
Aare ni kosi giri nipa wi pe boya eto idibo odun 2015 yoo waye tabi ko ni waye. Gege bi alaye Aare, o ni bo ti wu ki Boko Haram gbogun to, eto idibo maa waye dandan ni.
Ohun ti Aare so ni yii:
"I remember when I was in my village to collect my permanent voter card , a pressman asked me if there would be elections in Nigeria and I told him 'yes.'
"This country will continue to move on in spite of some of the setbacks we are witnessing. "
Pada sori waasu alufa Goodheart Ekwueme. Alufa ka oro Olorun lati inu iwe Esteri ori kerin ese ketala titi de metadinlogun (Esther 4:13-17). Alufa salaye wi pe Nigeria tuntun ko ni pe wa saye. Oniwaasu salaye awon nnkan to n sele yii bi igba ti abiamo fe bimo, eleyii to kun fun inira. Sugbon leyin ti omo tuntun ba ti wa saye, ara yoo tu iya omo ti gbogbo nnkan yoo si wa OK.
Awon oro to jade lati ori tabili mimo oniwaasu ni yii:
"The present situation in the country is just an indication of birth pains, we will go through the storms and a new Nigeria of our dreams and aspiration will soon be born.
"A Nigeria where there will be justice and equity will evolve.
A new Nigeria where corruption will become exemption rather than the rule will evolve; a county where every citizen will have a sense of belonging will evolve.
"When a child is born, the mother forgets the birth pains. So shall it be in Nigeria soon.
Lara awon eniyan ti won tele Aare lo josin papo lana ni olori ile igbimo asofin agba, David Mark; igbakeji olori ile igbimo asoju-sofin, Emeka Ihedioha; gomina ipinle Anambra nigba kan ri, Peter Obi; iya to bi Aare ati Patience Jonathan naa ke Hallelujay meje lati wo ogun Boko Haram lule womuwomu.
0 comments:
Post a Comment