Smiley face

Eye To Jabo Loju Ofurufu Di Eniyan Ni Ilu Eko

Ohun kayeefi kan sele lana ni agbegbe Ajegunle nigba ti eye nla kan sadeede jabo lati oju ofurufu to si yira pada di iya arugbo kan.



Iya naa jewo ara re gege bi ogbologbo aje, eleyii to wa lati ilu Ibadan si ilu Eko lati wa se awon ise akanse kan pataki pelu awon omo egbe agba meji mii.

Sugbon ona pooyi mo won loju nigba ti won n pada si ilu Ibadan. Iya naa salaye wi pe ibi awon ti n wa oju ona ni ile ti mo ba awon, igba ti o re oun lo fa ti oun fi jabo lule lati oju ofurufu.

Isele naa soju ogbeni Okafor, e je ka gbo ohun ti won ri.

"Immediately the bird landed on the van, it transformed into an old woman.

"Everyone ran away at first but we later gathered round the woman only to discover that she had a bruise on her forehead with which she landed.

"When we asked her what her mission was, she said three of them were sent to Lagos from their coven in Ibadan but that on their way back, they missed their way.

"She said they started hovering in the area until it was morning, adding that she fell because she was tired.

"She also told us that she initially did not want to embark on the journey and that she used to restrict her witchcraft activities to Ibadan because of her age.

"She was thereafter taken to the Baale of Ajeromi, where she confessed to have killed her husband through witchcraft."

Awon olopa ti dasi oro naa, won si ti toju iya naa pamo. Awon olopa ni kii se wi pe awon toju iya naa gege bi odaran bikose lati daabo bo o lowo awon eniyan ti won le fe le loko pa. Won ni labe ofin Nigeria, ko si ohun ti n je aje rara. Fun idi eyi, awon setan lati fa iya naa fun eyikeyi ebi re to ba yoju.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment