Smiley face

'Furo Mi Setan Fun Igbeyawo Alarinrin' - Omoge Onibadi Olokiki Agbaye

Kim Kardashian to je afesona gbajugbaja olorin ilu Amerika Kanye West, lo so oro yii ni ilu France nibi won ti n se faaji pelu eto imurasile igbeyawo won to n bo lona. Omobirin yii ko sadeede so iru oro bayii jade, sebi ti ko ba nidi obirin kii je Kumolu. 

O ti pe ti awon iwe iroyin amuludun agbaye ti maa n ko orisiirisii aroko nipa ibadi arabirin yii eleyii ti won ka si ohun ara oto. Yato si eleyii, aimoye ipolowo oja naa ni omobirin naa ti fi ibadi re se fun awon ile ise nlanla ni ilu Amerika. 

Lopin ohun gbogbo, omobirin naa ro wi pe o to asiko ki ibadi olokiki fidi mole fun igbadun oko re nikan. (oko re Kanye West yii ti fi igba kan  je bi oga si D'banj) 


Awon aworan orisiirisii obirin naa ni yii:


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment