Okunrin ara ilu China kan lo ko ebi re lo si ilu North Korea lati lo fun isinmi ranpe. Ilu North Korea naa ni won wa ki okan ninu awon omo re to so kaadi idanimo irinna (passport) re di 'drawing book' to si so aworan baba di oloju eja rabata. Okunrin naa gbiyanju lati pada sile bayii ni won ba ni koseese. Gbogbo alaye pata lo jasi pabo niwaju onibode ilu North Korea. Okunrin naa n gbiyanju lati wa ona ati gba Passport mii bayii pelu opolopo wahala. Oro naa su baba naa lo ba kuku fi aworan ara ti omo re da han gbogbo aye lori ayelukarabiajere.
#Gobe
0 comments:
Post a Comment