Smiley face

Tani Oba Oge?

Won ni omoge ti o laso oge kii rode ariya awon gbajumo. Sugbon ta ba n so nipa oge sise ati aso amurode to gbayi, oga ni Mercy Aigbe ati Adaeze to je iyawo Yobo agbaboolu.


Ninu awon mejeeji, nje tani ala pe ni oba oge pelu imura won fun toni, se Mercy ni tabi  Adaeze?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment