Iya obo yii lo gbiyanju lati wo ewu si orun ara re nigba toju kofiri. Sugbon kamera oloju merin ti n so ko seju rara. National Park to wa ni Borneo ni orileede Indonesia ni ara nla yii ti jeyo jade. E je ka wo awon aworan to ku
Iya Obo: Bawo ni mo se fe ki ese bo inu bata yii ?
Omo Obo: Iya mi, bata yen maa wa okay lori designer te e ju yen o
Iya Obo: O suo?
Iya Obo: Ewu yii ti fun mi ju joo
Omo Obo: E je tete 'Pull Over' ko to di Gobe
Omo Obo: Wahala de, Iya mi ti gan-an pa
Iya Obo: Ni o ba baba re lona orun. Omo ale.
Iya Obo: Iwo naa wo ko try e wo bo se ri.
Omo Obo: Iya mi, ko si were, saisi mi gangan laso yen sa
Omo Obo: Iya mi, DoroBucci laso yii. O make sense baje
Iya Obo: Iwo je kan kan e mo be
0 comments:
Post a Comment