nibi ti ado oloro ti gbe dun gbamu ti gbogbo oja si jona tan raurau. Awon kan so wi pe awon eniyan bi merinlelogoji lo ku, awon kan ni ogun eniyan lo sofo nibi isele ado oloro eleyii ti opolopo gba wi pe ara ise owo Boko Haram ni.
Titi di akoko yii, a ko tile so iye eniyan pato to ba isele naa lo.
E ku eti leko fun akotun iroyin tuntun.
0 comments:
Post a Comment