Ijamba oko to waye l'Ojobo (29/5/14) to koja yii lori afara Eko ni ilu Eko ti mu omo gomina Ipinle Oyo nigba kan ri, Senator Rashidi Ladoja lo. Ijamba oko to waye ni nnkan bi ago meta abo osan yii nibi ti oko Volkswagen Golf to je ti Adebola Ladoja ti lo ko sebe oko ajagbe kan ti oko ajagbe naa si wo oko omo Ladoja mole raurau bi igba eniyan fi ese pa aayan.
Eni ti oro naa soju re ba awon oniroyin soro:
“The victim would have survived the crash if the first set of people that arrived the scene had attempted to carry out first aid treatment.
“Rather, they were more concerned with forming a ring around the victim and taking pictures. Some of them however prevented the driver of the truck from running away when he tried to.
Agbenuso awon olopa Ipinle Eko ti jeri si isele buruku to waye yii, e gbo ohun ti won so:
“The accident occurred on Eko bridge when a Daf truck with registration number JJJ 59 XA driven by one Justice Oseghai ran into a Volkswagen Golf car with registration number AKD 107 CJ driven by one Adebola Ladoja, the son of the former governor of Oyo State, Senator Rasheed Ladoja.
“The victim died on the spot. The corpse has been moved to the Lagos Island General Hospital Mortuary for autopsy while the truck driver is in police custody.”
0 comments:
Post a Comment