Smiley face

"Oro Boko Haram Ko Ye Ijoba Nigeria Mo" Agbaoje Ologun Lati Ilu UK


Lori oro Boko Haram, Edumare nikan lo le ran wa lowo. Nitori agbara awon asaaju ti a gbokan le ti pin. Apileko kan jade lati ile ise iroyin BBC agbaye eleyii ti won pe akole re ni Why Nigeria has not defeated Boko Haram. Ninu apileko yii, awon oniroyin gba oro enu agbaoje ajagunfehinti ilu United Kingdom to tun je olori awon omogun ti Ilu Oba ran wa si ile Nigeria lati wa se iranlowo nipa awon omo ti Boko Haram jiko. 

E gbo ohun ti Ajagunfehiti James Hall so

"The trouble with the Nigerian government is that they want a big red button, which you can press and it will fix everything. I was asked by a senior commander if we could sell them the machine that can tell if a car driving down the road contains a terrorist. I tried to tell them that such a machine doesn't exist, but then they just thought we were hiding it from them."
E le ka iyokku apile ko naa NIBI
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment