Anastasia Tutik omo baba olowo to je eni odun mokandilogun(19) lo jabo pelu ololufe re to je eni odun mejidinlogun lati faranda to wa lori oke ile nibi won ti jo n se ere ife. Gege bi ohun ti a gbo, Anastasia Tutik sese pari idanwo re pelu akegbe re ni won ba se ajoyo opin idanwo won. Nibi won ti n yo naa ni won ti fi enu ko ara won lenu titi ere fi wonu ara won daada. Ti awon mejeeji si re jabo sile lojiji.
![]() |
Anastasia Tutik |
Omo Nigeria kan, Samson Oguntayo ti n gbe ni ila-oorun London ti isele naa soju re so ohun to ri nipa awon omo meji ti won ku yii.
'They were trying to have sex on the balcony. The guy was lifting the girl and putting her on the bannister, he kept on doing it.
‘He was putting her on there – they were going back and forth. You could see they were doing some really dangerous stuff.
‘It is not the first time we have seen people on the balcony acting up.
‘At some point friends must have come outside and they got down and came back inside and then came back out again. This time they started doing it again.
‘You see people on the balcony doing all sorts of things and I just felt it was one of those things and in a moment they will probably go back inside.
‘The last thing I expected was to see them falling down. We just screamed.’Igba ti Oguntayo yoo fi sare de ibi isele yii, inu agbara eje lo ti ba won. Ilu Russia ni awon obi omobirin yii wa, a si gbo wi pe nnkan bi milionu marun-un niye owo naira ni won san lowo ile iwe omo won lodoodun eleyii to pari gbogbo pelu iku ibanuje fun awon obi re.
![]() |
Samson Oguntayo |
0 comments:
Post a Comment