Okunrin yii ti fe pa ara re si ijoba lorun o. Ati igba to ti wo boolu Nigeria ati France tan ni ara re ko ti bale mo. Mo ni ko mokan ko gbagbe ohun to ti koja sugbon ko dahun. Ko to di wi pe oro yoo bo sori ni mo fi ni ki n ke gbajari o.
Iranlowo wo ni e le se fun un. John ni oruko re, ilu Abuja lo n gbe.

Iranlowo wo ni e le se fun un. John ni oruko re, ilu Abuja lo n gbe.

posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment