
Emi nìkan ni mo dá bọ́ọ̀lù tòní wo nílé. Mo sare dele ni pẹ̀lú ìrètí wi pe ìyanu o selẹ̀. Iyanu sì selẹ̀ Lóòótó, o kan jẹ wí pé omi pọ̀ ju ọkà lọ ni pẹ̀lú bi ayò náà se parí pẹ̀lú eeji si oodo. Ifesewonse naa bani lọ́kàn jẹ pẹ̀lu ilakaka àwọ̣n ọmọ wa.
A mọ,́ kò sí ohun ti a fẹ se.
Mo kí àwọ̣n ọmọ Super Eagles kú isẹ́ akoni gidi. Mo si beri fún wọn fun ẹ̀mí ifinsin ati jíjẹ olododo si ìlú taatibini.
Ki Oluwa bukun Naijeria.
Ki Oluwa si bukun ẹ̀yin naa pẹ̀lú.
posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment