Smiley face

Ija Nla Sele Ni Ile Ite Mimo To Wa Ni Ilu India

Sebi bayii la n se ni ile wa eewo ibo mii ni. Ni ilu India lonii nibi won ti n se adura ni iranti awon akoni to ku loju ija to waye lojo kefa osu kefa odun 1984 nibi ti aimyo awon eniyan ti padanu emi won. Ni ile ite mimo ti won pe ni Golden Temple ti Sikhism ni adura yii ti wa ye. 


Igba ti awon eniyan se adura tan ni won ba fa ida yo ti won si bere si ni ba ara awon ja bi igba eniyan wo India fiimu. 


Nje ki lo wa de? A bi eedi n di eyin pipu yii ni?

Won ni eedi ko di won. Won ni ara asa ati ise ni eleyii ti won n se lati ranti awon akoni to ku loju ija. Awon eniyan farapa nibi eto adura naa to wa ye lonii, ojo kefa osu kefa odun, koda osibitu nigbogbo awon to farapa wa bayii.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment