E ku atijo, se daada ni? Se alaafia le wa gbogbo ile nk o?
O ti to ojo meta ti ati ri WeirMC ati Tony Tetuila. Sugbon iyen gan-an ko ni koko inu iroyin.
Koko inu oroyin bayii ni wi pe WeirdMC ti gba ise iponlogo e-dibo-fun-Ogbeni-Rauf-Aregbesola lati wole leekeji gege bi gomina Ipinle Osun.
Boya 9ice ati Tony naa ti wa gbori wole, iyen ni mi o ni le dahun si. Sugbon gbogbo igba ni awon eniyan n ri won pa po.
0 comments:
Post a Comment