Smiley face

Kini E Ma Se Fun Kabiru To Ba Je Wi Pe Eyin Ni Baba Re?

Ka so wi pe igba meje otooto ni awon eyinbo ti dayin pada lai fun yin ni fisa ilu Amerika.

Igba ti won wa pada fun yin lase iwe irinna, lojo ti e fe tirafu gan-angan, Kabiru omo yin to je omo odun meji wa se kaadi idanimo okeere yin bayii.

E joo, ki ni ohun ti e maa se fun Kabiru?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment