Otunba Iyiola Omisore ti bẹ̀rẹ̀ si ni wọ inú ìgboro báyìí láti fi ẹnu ara rẹ polongo fun àwọn èniyàn. Nibi tí senato ti n polongo laaarin ọjà lo ti ra guguru oloyin to si bẹ̀rẹ̀ si ni je e. Nibi ti senato ti n je guguru lo ti wi ;
'Eyin eniyan mi-my people, E maa lo ro wi pe ajebota ni mi o, e saa ri bi mo ti n jẹ guguru oloyin. Mo ti pe ni Ghetto dáadáa, mo si mọ ibi ti bàtà ti n jẹ ara ilu lẹ́sẹ̀. Maa fe ki e fi ọwọ́ sowopo pẹ̀lú mi, ki Ipinle Osun le dara ju bayii lo.'

posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment