
Awon àwòrán díẹ̀ níbi ìseré fíìmù agbelewo. E gbọ́, se àwon àso ìbílẹ̀ yii yẹ Mercy Aigbe tabi ko yèé gẹ́gẹ́ bo ti wi? Maaki mélòó ni e le fún un lati ookan si eewa nípa bi asọ ìbílẹ̀ náà ti ye e to? Se maaki marun-un ni tabi méjọ? Abi maaki mẹ́ta ni èyin fẹ e fún?





posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment