Smiley face

Alufa E. A. Adeboye Ti Wa Dupe

Olori Ijo Irapada, Alufa E.O. Adeboye ti wa dupe lori Facebook nipa bi awon eniyan ti won ko din ni milionu meji se fi ife han sii lori Facebook.

Ninu pepa pelebe ti Daddy G.O mu dani ni baba ti wi pe;

"Thank you for #2 million friends.."
https://www.facebook.com/PastorEAAdeboye/likes

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment