Smiley face

E Wo Ibi Ti Bobo Yii Gbowo Le Lara Iyabo Ojo

Ka ma paro, Desmond Elliot yofa bebe yii. Abi eyin o ri wi pe ori apoti ijoko bebe naa lo gbe owo le ni?

Ti oko Iyabo Ojo ba je alara gbigbona, o daju wi pe ko ni like foto yii.

Sugbon sa, enu ise ni won wa. Ibi ise eni lasi ti n moni lole.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment