Smiley face

Awon Olopa Ti N Mu Number Ni Ilu London

Nibi ayeye Notting Hill Carnival ti n lo lowo ni Ilu London, awon osise alaabo ti won yan lati maa mojuto awon popona ti bere si ni mu nomba bayii.
Awon olopa naa ko tile le mu mora rara. Bi won se n kuru ni won ga, won tun pakurumo. Oga ju!



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment