Igbakeji gomina Ipinle Enugu, Ogbeni Sunday Onyebuchi ti je tan lonii nigba ti awon omo ile igbimo asofin ni ko ko eru re jade kuro ninu ile ijoba pelu esun wi pe o n sin adiye ni ile ijoba.
Bi o tile je wi pe oro naa ki se oju lasan nitori gomina ati igbakeji re ota ni won jo n se. Ohun ti agbalagba si fi n jeko, abe ewe lowa. Sibesibe, se won le fi eniyan je lemoomu ko tun ma du seriki?
0 comments:
Post a Comment