Ile ise iroyin CNN agbaye ti gbe ojo f'Aina nibi won ti n gbiyanju lati toka awon orileede ti arun Ebola n da laamu lowolowo bayii. Ilu Niger ni won naka si ninu afihan won gege bi orileede Nigeria. O ga oo!
Ilu Nigeria olokiki to fokula bi isana eleeta lo wa di ohun ti CNN o da mo bayii. Bi o tile je wi pe awon nnkan ti o da bi Boko Haram, Ebola naa ni won fi mo wa lagbaye. Eniwee, Dariz God ooo.
0 comments:
Post a Comment