![]() |
Awon ero bi ero Mecca ni Ilu Oshogbo |
Ipolongo Ogbeni Rauf Aregbesola ni yii ni ilu Oshogbo, nibi ti awon ero ti yapa bi ero Mecca.
Kini ero yin?
Ojo kesan-an osu kejo ni ojo ipade, nibi ti Omisore ati Aregbesola erujeje Baba Kabiru yoo ti jo maa na tan bi owo. Ibere kii se onise, eni to fori ti dopin ni a so di gomina ni Ipinle Osun.
Tani won pe ni Koro nibi tawa ti n soro? Koro ko...Kokoro ni.
#SIA 4+4. E File Beyen!- Adewale Dada The Good lo so bee
''Karimu...Karimu...wo gomina..gomina nu-un''
Awon eniyan n reti gomina ko koja
"I don't know who killed Bola Ige, only God knows that but I know that
the candidate of the PDP in Osun State was in jail in Agodi, and when he
wanted to nominate a minister, he chose Jelili my former commissioner,
they were both in Agodi, when they wanted to replace me as the National
Secretary, they picked Prof. Oladipo, they were both in Agodi together,
their proposed senatorial candidate in Osun Central was also with them
in Agodi prison.......Now some of us that are not criminals have been
marginalized. Why? Must we all go to prison or become criminals before
we can be relevant in the PDP?"- Prince Olagunsoye Oyinlola,ex-Gov Osun
State.
0 comments:
Post a Comment