Smiley face

E Ma Lo Ko Bami, Ile Oko Ni Mo Wa - Ronke Oshodi Oke

Ibi ti Taye ti yan ori, ibe ko ni Kehinde ti yan tie. Bi o tile je wi pe pupo awon irawo oserebirin ni won ko si ni ile oko kankan, Ronke Oshodi Oke ni beeko ni toun ri rara. Ati wi pe ki awon ti won so ohun oju won ko ri lo gbenu dake.

'Edumare se ade ori gidi fun mi, o si tun fun mi ni omo alalubarika. Ebe ni mo baye ki won maa fenu koba mi' Ronke Oshodi

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment