Ariya baba ariya tun wole de ni ilu London. Nibi ti
awon omoge onibadi aran yoo ti maa fi ibadi won dara orisiirisii ni
Notting Hills Carnival. Awon omo Naija to wa ni ilu London naa kii gba
rara, awon naa nibi ti won ti n sariya ti won legbe kan.
Odoodun
ni kanifa yii maa n waye ni ilu London, mo si fi dayin loju wi pe
gbogbo ariya naa ni maa mu wa fun yin lodindi. E gba mi gbo!
0 comments:
Post a Comment