Smiley face

Mercy Aigbe Lo Se Carnival Ni Ilu London

Ilu London ti bere si ni rokeke fun ayeye Notting Hill Carnival to maa n waye lodoodun, nibi ti ariya yoo ti maa san bi omi okun. Mercy Aigbe ti gbori wole, ojo to si ro lonii ni ilu London ko ni ko maa jade lo se faaji aye re.

Ariya sese bere ni, won tie ti bere si ni pidan. Asa, ilu, orin, efe ariya to ki lati ilu London, ori Olayemi Oniroyin nikan le o ti ri.
E ku faaji!


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment