Smiley face

Wizkid Ti Pada Dele Lati Oke Okun

Awon Yoruba ni ti oko ba rokun-rosa, dandan ni ko fori bale fun elebute. Ajo kosi le dun titi ki onile ma pada sile re.

Ilu Amerika ni Ibro ti n pariwo ko to pada si ilu London. Ilu London lo wa ni won tun fi iwe pe wi pe ko maa pada bo si New York ni ilu Amerika.

O ti pada dele bayii. Ile baba re lo wa ninu foto oke yii nigba to lo ki won kuule.

#Yaga

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment