Se ododo ni oro yii abi 9ice fi n sere lasan ni? O le je otito o. Nitori 9ice wa lara awon onise amuludun ti mo le so wi pe won ni itara mekunnu lokan gidigidi.
Sugbon ti 9ice ba n gbero lati gbe apoti idibo, labe egbe oselu wo ni; se PDP ni abi APC?
Omo Ogbomosho ni 9ice, o si wa lara awon olorin ti won polongo fun Alao Akala to je omo egbe PDP. Bakan naa ni Alapomeji wa lara awon olorin ti won polongo fun Ogbeni Aregbesola ti APC ninu idibo gomina to waye laipe yii.
Ibeere mi ni wi pe, egbe oselu won ni Bashorun Gaa fe ba lo?
0 comments:
Post a Comment