Ti party ijo ba ti ya, aso to gbamuse ni awon omoge asiko
fi n logba. Opin ose to koja ni ariya san, Iyabo Ojo debe pelu aso oge
to yaayi. Sebi omo to ba n sise deede, o ye ko lasiko faaji.
Ti eniyan ko ba ni figba kan bokan ninu. Oju omobirin naa mo fefe bi iyawo tuntun aganran ti enikeni ko fowo ba ri.
0 comments:
Post a Comment