Gege bi akosile iroyin to ti jade seyin, a ti nnkan bi osu keta odun ni awon omo agbegbon ti n pa opolopo awon eniyan ti won gbe ni agbegbe guusu Kaduna eleyii ti gomina ipinle naa, Mukhtar Yero ko lati yoju si awon eniyan naa lati ba won kedun.
Isele miiran tun sele lose to koja eleyii to wa mu gomina naa debe lana pelu aimoye soja oloju dudu fun aabo ara re. Bi awon eniyan se ri gomina, inu won ko dun rara. Won si bere si ni tu iro aso won lati fi ehonu ati ibanuje won han si gomina naa, eni ti won se apejuwe re gege bi odale, opuro, ati asaaju buruku.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment