Okan lara awon olori egbe awako Ipinle Eko to tun je omo egbe APC ti won seku pa, Alaaji Azeez Asake ni egbe APC ti gbe jade wi pe Musiliu Obanikoro lo wa nidi ise buruku naa.
Gege bi awijare won, won ni awon eniyan meji ti won fura si wi pe won pa Asake lo je wi pe odo Obanikoro ni won ti lo n gba owo buredi ati akara lojoojumo.
Ohun ti Ohimai Amaize to je agbenuso fun minisita naa so ni yii:
"For the record, Senator Obanikoro
emphatically disclaims the APC's statement as neither he nor any of his supporters has any connection with the murder of Alhaji Azeez Asake in any shape or form."
Ohun to pamo oju Olorun too.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment