Smiley face

Femi Adebayo Ti Gbe Ale Wale

E gbo se ika ni awon okunrin?

Ati wi pe ki lo buru ninu ki oko gbe ale wa sile lori beedi ti oun ati iyawo n sun?

Gege bi oro awon agba, won ni ojo gbogbo ni tole, ojo kan ni tolohun. Iyawo pada wale lojo ti oko n deku magolo pelu ale ninu yara.

Wahala, ijogbon, surutu, ariwo....

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment