Smiley face

AWON ALAKATAKITI ESIN ISLAM ISIS TI DU ORUN OMO ILE BIRITIKO BI ERAN ILEYA

David Cawthorne to je omo ile UK ni awon omo ISIS ti won ti pa awon oniroyin ilu Amerika meji kan seyin ti tun pitu owo won fun bayii.

Won ni awon seku pa okunrin naa latari bi ile UK se n se atileyin fun US nipa igbogun ti ile islam.

Oro enu okunrin apaayan naa ni yii:

'This British man has to the pay the price for your
promise, Cameron, to arm the Peshmerga against the Islamic State.

'Ironically he has spent a decade of his life serving
under the same Royal Air Force that is responsible for delivering those arms.

'Your evil alliance with America which continues to
strike the Muslims of Iraq and most recently bombed the Haditha Dam will only accelerate your destruction, and playing the role of the obedient lapdog, Cameron, will only drag you and your people into another bloody and unwinnable war.'

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment