Smiley face

Ara San Ni Manchester Nigba Ti Don Jazzy, Tiwa Savage, Dr Sid Ati Awon Olorin Mavin Dalu Bole

Awon eniyan to wa ni ilu Manchester lo le salaye ohun to sele lana nibi awon egbe olorin ile ise Mavin se bere si ni Doro pelu awon ololufe won ti won jade wa woran ayo.

Ilu London latun gbo wi pe ariya kan bayii nibi ti Don Jazzy, Tiwa Savage ati Dr DoroLere yoo ti maa pidan.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment