Notting Hill Carnival je ajoyo
eleyii to maa n waye lodoodun ni ilu United Kingdom. Gege bi itan se fi ye wa, odun 1966 lo bere,
osu kejo odun lo si maa n waye. Eleyii
to koja lo yii fee je eyi ti iroyin re jade ju lo lori olayemioniroyin.com. Opolopo awon eniyan ni
won si n kan si wa lati se afihan awon bebe, ara, ati idan to sele nibe leekan
sii. Idi ni yii ti mo fi sawon die jo fun igbadun yin.
Home / Amuludun /
Foto /
Iroyin Okeere
/ Awon Idan, Ara Ati Bebe To Sele Ni Notting Hill Carnival 2014 Ni Ilu London
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment