Smiley face

Oni Ni Ojo Ibi Amitabh Bachchan Osere Tiata Ilu India

Amitabh Bachchan je osere fiimu ilu India eleyii to gbajugbaja ni ilu Nigeria fun ise fiimu to ti gbese. Bi onirefin ko tile fingba mo, eyi to ti fin ko le parun.

Oni ni ojo ibi Amitabh Bachchan, a ki ku ori ire. Igba Odun, odun kan ni.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment