Awon aworan lati inu fiimu ti won pe akole re ni AHUN eleyii ti won n ya lowolowo.
Sugbon
sa, igbadun wa ninu ise fiimu fun awon okunrin. Bi Jelili se n ka mo
sikira lati eyin naa ni i fi owo gba ni igbaaya lekookan. Sebi ara ija
lehin wa. Oko ati iyawo ni won jo se ninu fiimu tuntun naa.
0 comments:
Post a Comment