Smiley face

Oga Ju: Owambe Ti Ilu Washington

Oga ju! Lojo iku eerin orisirisi obe leeyan n ri. Awon tiatia kan ni ilu Washington ni won jamisi ode ariya alankara alarinrin kan to waye ni ilu naa nibi ti Sule Alao Malaika ti korin. 

Awon foto bi ogorun ni won fi ranse si mi. Sugbon eyi to ka mi nisan ju ni ti "awon mummy" ti won fun gbogbo re papo soke. Se aya o ni maa dun won bayii? [Olayemi, kini problem e?] 

Nnkan meji ti won funpo soju kan soso gan-an ni problem mi. Erkk


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment