Smiley face

Ijamba Buruku Waye Laaro Oni Ni Ilu Abuja

Loju ona to lo si oja Wuse ni ijamba oko buruku naa ti waye eleyii to mu emi enikan lo loju ese nibi ti ijamba naa ti waye. Awon eniyan yoku ti won farapa ti dero osibitu nibi won ti n toju won bayii.

Ekunrere iroyin nbo laipe...

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment