Olori ile igbimo asoju-sofin, Aminu Waziri Tambuwal ti ni ki gbogbo awon ololufe oun lo mu okan bale wi pe ko sewu loko a fi giri aparo lasan. Oni gbogbo rukerudo ati fitinati ti n koju ohun kii se lasan, awon eniyan lo wa nidi oro, loro fi n ke.
Oni Aare Goodluck Jonathan, Emeka Ihedioha to je igbakeji olori ile, adajo agba ile Nigeria, Mohammed
Adoke ati Adamu Mu'azu to je alaga egbe PDP lapapo lowa lori oro oun.
Ninu oro re nigba to n ba awon oniroyin soro lo tun wi pe: " e wi fun won wi pe igba oko. Igba ada, won ba oke ja lasan ni. Oke o je, oke o mu, sibesibe oke lo bori gbogbo won pata. Won dite, won ba Oya ja lasan ni, Sango lo ni seere. "
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment