Smiley face

Awon Omo Aye Ti Pa Awako Gomina

Eni to je olori awako Gomina Umaru Al-Makura ti ipinle Nasarawa, Abdullahi Mairuwa ni awon kan ti seku pa laaro oni ojo Satide nigba ti won dabu ona re nigba ti okunrin naa n lo si ilu re pelu awon ebi re .
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment