Smiley face

Metala Ku, Ogoji Wa Ni Osibitu

Okere tan awon eniyan bi metala ni won ti je Olorun nipe ni Ilu Bauch nibi ado oloro iku kan ti dun gbamu nigba awon eniyan to lati gba owo lenu masiini ATM. Ojo Eti (7-11-14) to koja yii ni Azare to wa ni ijoba ibile Katagum ni isele yii ti sele, awon eniyan bi ogoji ni won si wa lesekan aye esekan orun bayii nibi won ti n gba itoju ni ile iwosan.

Awon onise ibi kan ni won wa so ado oloro onibeji naa sile nibi won ti n sebi eni wi pe awon naa fe gba owo lenu ATM ti opolopo awon eniyan po si naa.

Sugba sa, agbo wi pe awon olopa ti mu awon afura si meji kan to seese ki won lowo ninu ijamba buruku naa.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment