Arabirin Rose Aifuwa to je omo Nigeria to n gbe ni ilu Austria lo pada wale wa ba oko re fun odun keresi ati odun tuntun.
Sugbon oko re pinnnu lati seku paa latari owo tabua ati awon dukia to ti fi n ranse si oko re nigba to wa ni ilu Oyinbo.
Oko re fe je awon dukia naa mole ko le je tie nikan lo ba kuku seku pa Rose Aifuwa. Igba to pa tan ni o lo gbe oku re danu sorita ni ilu Bennin to wa ni Ipinle Edo.
Awon olopa ti mu okunrin to se ise buruku naa, o si ti jewo gbogbo iwa ibaje to wu niwa pata.
Die to ku ki odun pari, a ko ni sagbako iku ojiji. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment