Baalu AirAsia to gbera ni Indonesia to n lo si ilu Singapore to ye ko ti ba ni nnkan bi wakati meji seyin ni won ko ri ba yii. Ominu ti bere si ni ko awon alase ti oro naa kan ko ma lo je wi pe oju ojo ti ko daa lo ti se akoba fun baalu naa.
Afikun iroyin mbo laipe..
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment