Ile ise iroyin BBC agbaye ti je ka rigbo wi pe baalu to gbera ni Indonesia lo si Singapore eleyii to poora laaro oni ni enikeni ko ti le so ibi to wole si bayii.
Infomasan baalu naa ni yii:
Ile ise to ni baalu naa: Asia Air
Iye eniyan to wa ninu baalu naa: 162
Nomba Baalu naa: QZ8501
Home / Uncategories / "Sibesibe, Won Ko Ti Ri Baalu To Poora Loju Orun Laaro Oni" - Ile Ise Iroyin BBC Agbaye
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment