Smiley face

Funke Akindele ,Ice Prince, MI, Olamide,Uti ,Banky W Ti Bere Ipolongo Fun Ambode Ni Ilu Eko

Awon agba amuludun ti bere ipolongo fun oludije fun ipo gomina labe egbe APC fun ipinle Eko, Akinwunmi Ambode. Lara awon ti won ti setan lati duro leyin egbe onigbale ni Funke Akindele ,Ice Prince, MI, Olamide,Uti ,Banky W ati bee bee lo.




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment