Moto gba omokunrin kan laaro oni ni ibudoko Ojota loju ona Ikorodu nigba to fe sare fo titi, Oju ese naa ni omokunrin naa je Olorun nipe. Moto to gba omokunrin naa ko si duro rara. Bo se gba tan lo salo.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment